Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 40:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ní ọdún kẹẹdọ́gbọ̀n tí a ti wà ni oko ẹrú wa, ní ìbẹ̀rẹ̀ ọdún, ni oṣù kẹwàá ọdún kẹ́rinlá lẹ́yin ìsubú ìlú ńlá náà ní ọjọ́ náà gan an ọwọ́ Olúwa ń bẹ̀ lára mi, oùn sì mú mi lọ síbẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 40

Wo Ísíkẹ́lì 40:1 ni o tọ