Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 4:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ló wí fún mi pé, “Wò ó, Èmi ó fún ọ ní ìgbẹ́ màlúù dípò ìgbẹ́ ènìyàn. Èmi yóò mú ki ó dín àkàrà rẹ lórí ìgbẹ́ màlúù dípò igbẹ ènìyàn.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 4

Wo Ísíkẹ́lì 4:15 ni o tọ