Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 4:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni mo wí pé, “Áà! kò rí bẹ́ẹ̀ Olúwa Ọlọ́run! Láti ìgbà èwe mi di ìsinsìnyìí èmi kò tí ì sọ ara mi di aláìmọ́ rí. Èmi kò tí ì jẹ ohun tó kú fúnra rẹ̀ tàbí èyí tí ẹranko búburú fàya pẹ́rẹpẹ̀rẹ. Bẹ́ẹ̀ ni ẹran àìmọ́ kan kò tí ì wọ ẹnu mi rí.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 4

Wo Ísíkẹ́lì 4:14 ni o tọ