Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 37:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò so ìṣan ara mọ́ ọn yín, èmi yóò sì mú kí ẹran ara wá sí ara yín, èmi yóò sì fi awọ ara bò yín: Èmi yóò sì fi èémí sínú yín, ẹ̀yin yóò sì wà ní ààyè. Nígbà náà ẹ̀yin yóò mọ̀ pé èmi ni Olúwa.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 37

Wo Ísíkẹ́lì 37:6 ni o tọ