Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 37:26 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò dá májẹ̀mu àlàáfíà pẹ̀lú wọn, yóò sì jẹ́ májẹ̀mu títí ayérayé. Èmi yóò gbé wọn kalẹ̀, èmi yóò sì ṣọ wọ́n di púpọ̀ ní iye, èmi yóò sì gbé ilé mímọ́ mi kalẹ̀ ní àárin wọn títí láé.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 37

Wo Ísíkẹ́lì 37:26 ni o tọ