Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 37:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Dáfídì ìránṣẹ́ mi ni yóò jẹ Ọba lórí wọn, gbogbo wọn yóò sì ní olùṣọ àgùntàn kan. Wọn yóò sì tẹ̀lé òfin mi, wọn yóò sì ṣe àníyàn láti pa àṣẹ mi mọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 37

Wo Ísíkẹ́lì 37:24 ni o tọ