Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 35:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá:

2. “Ọmọ ènìyàn kọjú sí òkè Séírì; ṣọtẹ́lẹ̀ síi

3. Kí o sì sọ wí pé: ‘Èyí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí: Èmí lòdì sí ọ, òkè Séírì, Èmi yóò sì na ọwọ́ mi síta ní ìlòdì sí ọ, èmi yóò sì mú kí o di ahoro.

4. Èmì yóò pa àwọn ìlú rẹ run, ìwọ yóò sì di ahoro. Nígbà náà ni ìwọ yóò mọ̀ pé èmi ni Olúwa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 35