Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 34:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ṣé oúnjẹ jíjẹ ní pápá oko tútù dídára kò tó yín! Ṣé ó jẹ́ dandan fún ọ láti fi ẹsẹ̀ tẹ pápá oko tútù rẹ tí ó kù? Ṣé omi tí ó tòrò kò tó fún yín ní mímu? Ṣe dandan ni kí ó fi ẹrẹ̀ yí ẹsẹ̀ yín?

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 34

Wo Ísíkẹ́lì 34:18 ni o tọ