Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 33:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà ti mo bá sọ fún ẹni búburú pé, ‘A! ẹni búburú, ìwọ yóò kú dandan,’ ti ìwọ kò sì sọ̀rọ̀ síta láti yí i lọ́kàn padà kúrò ni ọ̀nà rẹ̀ gbogbo, ẹni búburú náà yóò kú nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀, èmi yóò sì bèèrè ẹ̀jẹ̀ rẹ̀ lọ́wọ́ rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 33

Wo Ísíkẹ́lì 33:8 ni o tọ