Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 32:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí mo bá fọ́n ọ jáde, èmi yóò pa ọ̀run déàwọn ìràwọ̀ wọn yóò sì ṣókùnkùn;èmi yóò sì fi ìkùukùu bo oòrùnòṣùpá kì yóò sì tan ìmọ́lẹ̀ rẹ̀

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 32

Wo Ísíkẹ́lì 32:7 ni o tọ