Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 32:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Láti inú isà òkú alágbára tí í ṣe aṣáájú yóò sọ nípa Éjíbítì àti àwọn àlejò rẹ̀, ‘Wọn ti wá sí ìsàlẹ̀, wọn sì sùn pẹ̀lú aláìkọlà, pẹ̀lú àwọn tí a fi idà pa.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 32

Wo Ísíkẹ́lì 32:21 ni o tọ