Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 32:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ ènìyàn, ṣe ìpohùnréré ẹkún nítorí Fáráò Ọba Éjíbítì kí o sì wí fún un:“ ‘Ìwọ dàbí kìnnìún láàárin àwọnorílẹ̀ èdè náà;ìwọ dàbí ohun abanilẹ́rù inú àwọn okun to ń lọkáàkiri inú àwọn odò rẹ,ìwọ fi ẹsẹ rẹ tẹ omiláti mú kí àwọn odò ní ẹrẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 32

Wo Ísíkẹ́lì 32:2 ni o tọ