Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 30:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lẹ́yìn náà wọn yóò mọ̀ pé èmi ní Olúwa,nígbà tí mo bá gbé iná kalẹ̀ ní Ijíbítìtí gbogbo àwọn olùrànlọ́wọ́ rẹ̀ bá parun.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 30

Wo Ísíkẹ́lì 30:8 ni o tọ