Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 30:14-16 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

14. Èmi yóò sì mú kí Pátírọ́sì di ahoroèmi yóò fi ina sí Sóánìèmi yóò sì fi ìyà jẹ Tébésì

15. Èmi yóò tú ìbínú mi jáde sórí Pélúsíómùìlú odi Éjíbítìèmi yóò sì ké àkójọpọ̀ Jépésì kúrò

16. Èmi yóò ti iná bọ ÉjíbítìPélúsíómù yóò japoró ní ìroraÈfúùfù yóò jà ní TébésìMémìfísì yóò wà ìpọ́njú ní ìgbà gbogbo

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 30