Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 3:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà náà ni mo lọ sí etí odò Kébárì níbi tí àwọn ìgbèkùn ń gbé ni Teli-Ábíbì. Níbẹ̀ níbi tí wọ́n ń gbé, mo jókòó láàrin wọn pẹ̀lú ìyànu, fún ọjọ́ méje.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 3

Wo Ísíkẹ́lì 3:15 ni o tọ