Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 3:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Lọ nísinsìnyìí sí ọ̀dọ̀ àwọn ènìyàn rẹ tó wà ní ìgbèkùn. Sọ fún wọn pé báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí yálà wọ́n gbọ́ tàbí wọn kò gbọ́.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 3

Wo Ísíkẹ́lì 3:11 ni o tọ