Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 28:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Kì yóò sì sí ẹ̀gún tí ń gun ni ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì mọ́, tàbí ẹ̀gún bíbani nínú jẹ́ ti gbogbo àwọn tí wọn wà ní àyíká wọn, tí wọ́n sì ń fi ojú yẹpẹrẹ wò wọ́n, nígbà náà ni wọn yóò mọ́ wí pé èmi ni Olúwa Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 28

Wo Ísíkẹ́lì 28:24 ni o tọ