Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 28:22 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ó sì wí pé: ‘Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Èmi lòdì sí ọ, ìwọ Sídónì,a ó sì ṣe mí lógo láàárin rẹ.Wọn yóò, mọ̀ pé èmi ní Olúwa,Nígbà tí mo bá mú ìdájọ́ mi ṣẹ nínú rẹtí a sì yá mí sí mímọ́ nínú rẹ,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 28

Wo Ísíkẹ́lì 28:22 ni o tọ