Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 28:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nípa ẹ̀ṣẹ̀ púpọ̀ rẹ àti òwò àìsòótọ́ rẹìwọ ti ba àwọn ibi mímọ́ rẹ jẹ́.Nítorí náà mo mú kí iná jáde wá látiinú rẹ, yóò sì jó ọ run,èmi yóò sì sọ ọ́ di eérú lórí ilẹ̀lójú gbogbo àwọn tí ó ń wò ọ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 28

Wo Ísíkẹ́lì 28:18 ni o tọ