Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 28:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ ènìyàn, pohùnréré ẹkún sórí ọba Tírè kí ó sì sọ fún un pé: ‘Èyí yìí ni ohun tí Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Ìwọ jẹ́ àpẹrẹ ìjẹ́pípé náào kún fún ọgbọ́n,o sì pé ní ẹwà

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 28

Wo Ísíkẹ́lì 28:12 ni o tọ