Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 28:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọ̀rọ̀ Olúwa tún tọ̀ mí wá wí pé:

2. “Ọmọ ènìyàn, sọ fún ọmọ-aládé Tírè pé, ‘Báyìí ní Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Nítorí tí ọkàn rẹ gbé sókè simiìwọ wí pé, “Èmi ni Ọlọ́run;Èmi jókòó sí orí ìtẹ́ òrìṣàní àárin gbùngbùn òkun.”Ṣùgbọ́n ènìyàn ni ọ́, kì i ṣe òrìṣà,bí ó tilẹ̀ jẹ́ wí pé ìwọ rò pé ìwọ gbọ́n bí Ọlọ́run.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 28