Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 27:8 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ará ìlú Sídónì àti Árífádì ni àwọn ìtukọ̀ rẹ̀àwọn ọlọ́gbọ́n ẹ̀rọ rẹ, ìwọ Tírè,tí wọ́n wà nínú rẹ ni àwọn àtukọ̀ rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 27

Wo Ísíkẹ́lì 27:8 ni o tọ