Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 27:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn ènìyàn Árífádì àti Hélékìwà lórí odi rẹ yíká;àti àwọn akọni Gámádì,wà nínú ilé ìṣọ́ rẹ.Wọ́n fi àwọn asà wọn kọ ara odi rẹ;wọn ti mú ẹwà rẹ pé.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 27

Wo Ísíkẹ́lì 27:11 ni o tọ