Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 27:1-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ọ̀rọ̀ Olúwa tún tọ̀ mí wá wí pé:

2. “Ọmọ ènìyàn, pohùnréré ẹkún fún Tírè.

3. Sọ fún Tírè, tí a tẹ̀dó sí ẹnu bodè òkun, oníṣòwò àwọn orílẹ̀-èdè fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù. ‘Èyí yìí ní Olúwa Ọlọ́run wí:“ ‘Ìwọ Tírè wí pé“Ẹwá mi pé.”

4. Ààlà rẹ wà ní àárin òkun;àwọn ọ̀mọ̀lé rẹ ti mú ẹwà rẹ pé.

5. Wọn ti fi pákó firi ti Sénárìkan gbogbo ọkọ̀ rẹ,wọ́n ti mú kédárì ti Lébánónì wáláti fi ṣe òpó ọkọ̀ fún ọ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 27