Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 25:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí pé: ‘Nítorí pé Édómù gbẹ̀san lára ilé Júdà, ó sì jẹ̀bi gidigidi nípa síse bẹ́ ẹ̀,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 25

Wo Ísíkẹ́lì 25:12 ni o tọ