Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 24:25 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Pẹ̀lúpẹ̀lù ìwọ, Ọmọ ènìyàn, kì yóò ha jẹ́ pé, ní ọjọ́ náà, nígbà ti mo bá gba agbára wọn, ayọ̀ wọn àti ògo wọn, ìfẹ́ ojú wọn, ohun tí wọn gbé ọkàn wọn lé, àti àwọn ọmọ ọkùnrin wọn pẹ̀lú àwọn ọmọ obìnrin wọn kúrò lọ́dọ̀ wọn,

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 24

Wo Ísíkẹ́lì 24:25 ni o tọ