Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 24:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ísíkẹ́ẹ̀lì yóò jẹ àmì fún un yín; ẹ̀yin yóò sì ṣe gẹ́gẹ́ bí òun ti ṣe. Nígbà tí èyí bá sẹlẹ̀, ẹ̀yin yóò mọ̀ pé èmi ni Olúwa Ọlọ́run.’

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 24

Wo Ísíkẹ́lì 24:24 ni o tọ