Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 22:29 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn enìyàn ilẹ̀ náà, tí lo ìwà ìnínilára, wọn sì já olè, wọn sì ni àwọn tálákà àti aláìní lára; nítòótọ́, wọn tí ní àlejò lára láìnídí. Kò sì sí ìdájọ́ òdodó.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 22

Wo Ísíkẹ́lì 22:29 ni o tọ