Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 20:24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

nítorí pé wọn kò pa òfin mí mọ́, wọn sì tún kọ àsẹ mi sílẹ̀, wọn tún sọ ọjọ́ ìsinmi mi di aláìmọ́. Ọkàn wọn sì dúró ṣinṣin sọ́dọ̀ òrìṣà baba wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:24 ni o tọ