Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 20:21 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Ṣùgbọ́n àwọn ọmọ náà ṣọ̀tẹ̀ sí mi. Wọn kò tẹ̀lé àṣẹ mi, wọn kò sì pa òfin mí mọ́ bí o tilẹ̀ jẹ́ pé ẹni tó bá tẹ̀lé àwọn òfin yìí, yóò yè nínú rẹ̀, wọ́n sì tún sọ ọjọ́ ìsinmi mi di aláìmọ́. Nítorí náà, mo sọ pé ń ó tú ìbínú mi lórí wọn N ó sì mú kí ibínú gbígbóná mi wá sórí wọn ni ihà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 20

Wo Ísíkẹ́lì 20:21 ni o tọ