Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 19:5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Nígbà tí abo kìnìún yìí rí pé ìrètí rẹ̀ sì já sí asán,ó mú ọmọ rẹ̀ mìíràn ó sì tún tọ́ ọ dàgbà di kìnnìún tó ní agbára.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 19

Wo Ísíkẹ́lì 19:5 ni o tọ