Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 18:6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

tí kò bá wọn jẹun lórí òkè gíga,tí kò gbójú rẹ̀ sókè sí àwọnòrìṣà ilẹ̀ Ísírẹ́lì, ti kò sì báobìnrin aládùúgbò rẹ̀ jẹ́ tàbí kí ósùn ti obìnrin ni àsìkò èérí rẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 18

Wo Ísíkẹ́lì 18:6 ni o tọ