Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 18:20 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọkàn tí ó bá sẹ̀ ní yóò kú. Ọmọ kò ní í ru ẹ̀bi baba rẹ̀ bẹ́ẹ̀ ni baba náà kò ní i ru ẹ̀bi ọmọ rẹ̀. Ìwà rere ènìyàn rere yóò wà lórí rẹ̀, ìwà búburú ti ènìyàn búburu náà la ó kà síi lọ́rùn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 18

Wo Ísíkẹ́lì 18:20 ni o tọ