Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 18:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Síbẹ̀, ẹ tún ń bèèrè pé, ‘Kí ló dé ti ọmọ kò ní í ru ẹ̀bi baba rẹ̀?’ Níwọ̀n ìgbà tí ọmọ ti ṣe ohun tó tọ́, tó sì yẹ, tó sì ti kíyè sí ara láti pa gbogbo àṣẹ mi mọ́, nítòótọ́ ni pé yóò yè.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 18

Wo Ísíkẹ́lì 18:19 ni o tọ