Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 16:34 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nínú àgbèrè rẹ ìwọ yàtọ̀ sí àwọn alágbèrè obìnrin yòókù; kò sí ẹni tó ń wá ọ fún àgbèrè. Ìwọ ló ń sánwó: nígbà tí wọn yóò sanwó fún ọ, ìdákejì ni ọ́; nítorí pé ìwọ ló ń sanwo bẹ́ẹ̀ ni ìwọ kò rí gbà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 16

Wo Ísíkẹ́lì 16:34 ni o tọ