Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 14:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“ ‘Bí ẹnikẹ́ni ní ilé Ísírẹ́lì tàbí àlejò tó ń gbé ní ilẹ̀ Ísírẹ́lì, bá ya ara rẹ̀ kúrò lọ́dọ̀ mi, tó gbé òrìṣà rẹ̀ sọ́kàn rẹ̀, tó tún gbé ohun tó ń mú ni ṣubú sínú ẹ̀ṣẹ̀ ṣíwájú rẹ, lẹ́yìn èyí tó tún lọ sọ́dọ̀ wòlíì láti béèrè nǹkan lọ́wọ́ mi! Èmi Olúwa fúnra ara mi ní ń o dá a lóhùn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:7 ni o tọ