Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 14:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

‘Báyìí ni Olúwa Ọlọ́run wí: Bí ẹnikẹ́ni ní ilé Ísírẹ́lì tó ó gbé òrìṣà sí ọkàn wọn, tó tún gbé ohun ìkọ̀sẹ̀ ṣíwájú rẹ̀, bá wá sọ́dọ̀ wòlíì, Èmi Olúwa fúnra mi ni n ó dá a lóhùn gẹ́gẹ́ bí ìwà ìbọ̀rìṣà rẹ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:4 ni o tọ