Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 14:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí ẹ bá rí ìwà àti ìṣe wọn, a ó tù yín nínú, nítorí pé ẹ ó mọ̀ pé n kò ṣe nǹkan kan láì nídìí, ni Olúwa Ọlọ́run wí.”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:23 ni o tọ