Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 14:18 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Bí àwọn ọkúnrin mẹ́ta yìí tilẹ̀ wà nínú rẹ̀, Olúwa Ọlọ́run wí pé, Bí mo ti wà, wọn ki yóò gba ọmọkúnrin tàbí ọmọbìnrin là, ṣùgbọ́n àwọn tikara wọn nìkan ni a o gbàlà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:18 ni o tọ