Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 14:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Kí ilé Ísírẹ́lì má baà sìnà kúrò lọ́dọ̀ mi tàbí kí wọ́n má baà sọra wọn di aláìmọ́ torí ẹ̀ṣẹ̀ wọn. Ṣùgbọ́n kí wọ́n le jẹ́ ènìyàn mi, kí Èmi náà sì le jẹ́ Ọlọ́run wọn, ni Olúwa Ọlọ́run wí.’ ”

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 14

Wo Ísíkẹ́lì 14:11 ni o tọ