Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 13:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Báyìí ni N ó ṣe lo ìbínú mi lórí odi yìí àti àwọn to fi amọ̀ àìpò rẹ́ ẹ, tí wọ́n sì fi ẹfun kùn ún. N ó sì sọ fún yín pé, “Kò sí odi mọ́, bẹ́ẹ̀ ni àwọn tó rẹ́ ẹ náà kò sí mọ́;

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:15 ni o tọ