Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 13:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi yóò wó ògiri tí ẹ fi amọ̀ àìpò rẹ́, èyí tí ẹ fi ẹfun kùn lulẹ̀ débi pé ìpìlẹ̀ rẹ yóò hàn jáde. Nígbà ti odi náà wó palẹ̀, a ó sì run yín sínú rẹ̀, ẹ ó sì mọ̀ pé Èmi ni Olúwa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 13

Wo Ísíkẹ́lì 13:14 ni o tọ