Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 12:21-24 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

21. Ọ̀rọ̀ Olúwa tọ̀ mí wá pé:

22. “Ọmọ ènìyàn, irú òwé wo lẹ ń pa nílẹ̀ Ísírẹ́lì pé: ‘A fa ọjọ́ gùn, gbogbo ìran di asán’?

23. Sọ fún wọn, ‘Èmi yóò fi òpin sí òwe yìí, wọn kò ní ipa mọ́ ní Ísírẹ́lì.’ Sọ fún wọn, ‘Ọjọ́ náà súnmọ́ tòsí nígbà tí gbogbo ìran àti ìsọtẹ́lẹ̀ yóò sì wá sí ìmúṣẹ́.

24. Nítorí kò ní sí ìran asán tàbí àfọ̀ṣẹ yẹ̀yẹ́ mọ́ láàrin ilé Ísírẹ́lì.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12