Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 12:23 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sọ fún wọn, ‘Èmi yóò fi òpin sí òwe yìí, wọn kò ní ipa mọ́ ní Ísírẹ́lì.’ Sọ fún wọn, ‘Ọjọ́ náà súnmọ́ tòsí nígbà tí gbogbo ìran àti ìsọtẹ́lẹ̀ yóò sì wá sí ìmúṣẹ́.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12

Wo Ísíkẹ́lì 12:23 ni o tọ