Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 12:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ọmọ aládé tó wà láàrin wọn yóò di ẹrù rẹ lé èjìká lálẹ́ yóò sì jáde lọ, òun náà yóò da ògiri lu kí ó le gba ibẹ̀ jáde. Yóò sì bo ojú rẹ̀ kí ó má ba à rí ilẹ̀.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 12

Wo Ísíkẹ́lì 12:12 ni o tọ