Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 10:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì rí i pé kẹ̀kẹ́ mẹ́rin wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ àwọn kérúbù yìí, kẹ̀kẹ́ kọ̀ọ̀kan wà lẹ́gbẹ̀ẹ́ kérúbù kọ̀ọ̀kan; àwọn kẹ̀kẹ́ yìí ń tàn yanran bí àpapọ̀ àwọ̀ ewéko àti pupa rẹ́súrẹ́sú.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 10

Wo Ísíkẹ́lì 10:9 ni o tọ