Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 10:7 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ọ̀kan nínú àwọn kérúbù sì nawọ́ síbi iná tó wà láàrin kérúbù yóòkù. Ó mú lára rẹ, ó fi sínú ọwọ́ ọkùnrin aláṣọ funfun, òun náà gbàá, ó sì jáde lọ.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 10

Wo Ísíkẹ́lì 10:7 ni o tọ