Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 10:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ògo Olúwa sì kúrò lórí àwọn kérúbù, ó bọ́ sí ibi ìloro tẹ́ḿpìlì. Ìkùukùu sì bo inú tẹ́ḿpìlì, àgbàlá sì kún fún ìmọ́lẹ̀ àti ògo Olúwa.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 10

Wo Ísíkẹ́lì 10:4 ni o tọ