Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 10:19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Àwọn kérúbù gbé ìyẹ́ wọn sókè, wọ́n sì fò kúrò nílẹ̀ lójú mi, wọ́n sì lọ pẹ̀lú kẹ̀kẹ́ wọn lẹ́ẹ̀kan náà. Wọ́n dúró níbi ìlẹ̀kùn ẹnu ọ̀nà ìlà-oòrùn ilé Olúwa, ògo Ọlọ́run Ísírẹ́lì sì wà lórí wọn.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 10

Wo Ísíkẹ́lì 10:19 ni o tọ