Atijọ Majemu

Majẹmu Titun

Ísíkẹ́lì 10:11 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nígbà tí wọ́n ń lọ, wọ́n tẹ̀lé ọ̀kan nínú ọ̀nà mẹ́rin tí àwọn kérúbù dojú kọ; àwọn kẹ̀kẹ́ náà kò yípadà bí àwọn kérúbù ti ń lọ. Àwọn kérúbù ń lọ síbi tí orí dojú kọ láì yà.

Ka pipe ipin Ísíkẹ́lì 10

Wo Ísíkẹ́lì 10:11 ni o tọ